Matthew 5:1-2

Ìwàásù orí òkè

1 aNígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá. 2Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn.

Ó wí pé:

Copyright information for YorBMYO